Search This Blog
Friday, November 30, 2018
IFEMI
Ife a ma muni eni dun
Ife a ma pani lerin
Ife a ma pani bi oti
Ife dabi Igi araba ti akole fi owo shinidi
Ife ama fe eni, Ke eni,
Gun eni, toni, gbani, lani,
ba eni wi, to ju eni, duro tini
gboniye, fori ti eni, fola fun ni, ja fun ni
Ife kin sun, Ife kin toun gbe
Ife kin ti, Ife kin sa
Ife kin dibaje
Awele mi owon,
Iwo ni Ifemi
Eni to ba bami ri Omo Onile kan, Ona kan,
ko ba mi kee fun wipe
Ife re ti gba gbogbo okan mi
Oluwajuwonlo Ayobosedemi
Omo ti aba ke
Omo ti ko we to n dan
Adu mara dan mi
Omo rewa, oni iwa,
Omo to ju won lo,
Ololufemi, Eeyan mi
Erin re asi ma mu inu mi yo
Eni ri e, o ra yo
Idunu Obi
Omo dun ke
Omo Kosalamala ni ilu Babanloma
Omo baba Teacher
IyanuME
Subscribe to:
Comments (Atom)